Yo PO

From OLPC
Jump to: navigation, search
This PO file is used for the translation of the OLPC website based on the template (POT) file.  Feel free to make corrections; please use the talk page for your comments.
# Internationalization for the OLPC website
# Source language: "en-US"
# Target language: "yo"
# Version: 1.1
# Date: 12 March 2006
# Author: Walter Bender
# Translator: Fajuyitan, Sunday Ayo <ayo@wazobialinux.com>
"Project-Id-Version: olpc\n"
"POT-Creation-Date: 2006-02-14 12:00-0500\n"
"PO-Revision-Date: 2006-08-11 12:36+0100\n"
"Last-Translator: Fajuyitan, Sunday Ayo <ayo@wazobialinux.com>\n"
"Language-Team: Yoruba\n"
"MIME-Version: 1.0\n"
"Content-Type: text/plain; charset=UTF-8\n"
"Content-Transfer-Encoding: 8bit\n"
"X-Generator: KBabel 1.10\n"

msgid "align"
msgstr "left"

#: laptop.html
msgid "title"
msgstr "Kọ̀ǹpútà Alágbèéká fún Ọmọ Kọ̀ọ̀kan"

msgid "intro"
msgstr "Introducing the children's laptop from One Laptop per Child—a potent learning tool created expressly for the world's poorest children living in its most remote environments. The laptop was designed collaboratively by experts from both academia and industry, bringing to bear both extraordinary talent and many decades of collective field experience in every aspect of this non-profit humanitarian project. The result is a unique harmony of form and function; a flexible, ultra low-cost, power-efficient, responsive, and durable machine with which nations of the emerging world can leapfrog decades of development—immediately transforming the content and quality of their children's learning."

msgid "content"
msgstr "Kọ̀ǹpútà Alágbèéká fún Ọmọ Kọ̀ọ̀kan (OLPC) jẹ́ àjọ aṣẹ̀dá lá́ńfààní tó fira wọn jìn fún ìwádìí-ìjìnlẹ̀ láti lè ṣe kọ̀ǹ́pútà alágbèéká $100—ìmọ̀-ẹ̀rọ tí ó lè mú ìyípadà ọ̀tun bá bí a ṣe ń kọ́ àwọn ọmọdé àgbáyé lẹ́kọ̀ọ́."

msgid "language"
msgstr "Yorùbá"

msgid "navhome"
msgstr "ILÉ"

msgid "navwiki"
msgstr "WIKI"

msgid "navcommunity"
msgstr "ÌRÒYÌN ÌLÚ"

msgid "navfaq"
msgstr "FAQ"

msgid "navpeople"
msgstr "ÈNÌYÀN"

msgid "navpress"
msgstr "ÌGBÉRÒYÌNJÁDE"

msgid "navdownload"
msgstr "ÌGBÉRÒYÌN WỌLÉ"

msgid "navmap"
msgstr "MÁÀPÙ"

msgid "navcontact"
msgstr "KÀN SÍ OLPC"

msgid "homebody1"
msgstr "Kọ̀ǹpútà Alágbèéká fún Ọmọ Kọ̀ọ̀kan (OLPC) jẹ́ àjọ aṣẹ̀dá lá́ńfààní tó fira wọn jìn fún ìwádìí-ìjìnlẹ̀ láti lè ṣe kọ̀ǹ́pútà alágbèéká $100—ìmọ̀-ẹ̀rọ tí ó lè mú ìyípadà ọ̀tun bá bí a ṣe ń kọ́ àwọn ọmọdé àgbáyé lẹ́kọ̀ọ́. Nicholas Negroponte tó jẹ́ alága OLPC ní àjọ World Economic Forum ní ìlú Davos, Switzerland ní Jánúárì 2005 ló kọ́kọ́ kéde ète yìí. "

msgid "homebody2"
msgstr "Ibi tí a fẹ́dé: ni láti lè pèsè àwọn àǹfààní fún àwọn ọmọdé kárí-ayé láti lè ṣàbẹ̀wò, àṣerò kí wọ́n sì lè fi èrò-ọkàn wọn hàn. "

msgid "homebody3"
msgstr "Jọ̀wọ́ kíyèsí pé àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká $100 náà—kò tí ì kúrò níbi tí a ti ń ṣe wọ́n—a kò dẹ̀ ní tà wọ́n. Àwọn ilé-ìwé nìkan la máa pín àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká náà fún tààrà nípasẹ̀ àwọn ète ìjọba ńlá. "

msgid "peoplebody1"
msgstr "ÀWỌN Ọ̀GÁ ILÉ-ÌWÉ"

msgid "peoplebody2"
msgstr "ÀWỌN OLÙDÁMỌ̀RÀN "

msgid "peoplebody3"
msgstr "Wo bios nípa títẹ̀ lórí wúnrẹ̀n àtòjọ-ẹ̀yàn ÈNÌYÀN. "

msgid "wikibody1"
msgstr "WIKI là ń lò fún ìdáwọ́lé náà, níbẹ̀ la sì máa ń pe ilù sí láti jíròrò: (1)ẹ̀yà-ara kọ̀ǹpútà afojúrí; (2) ẹ̀yà-ara kọ̀ǹpùtà àìfojúrí; (3) àkóónú ètó-ẹ̀kọ́; (4) àwọn ètò ìfilọ́lẹ̀; (5) bí ẹ ṣe lè dá si; àti (6) ṣàfikún àwọn ìbéèrè sí FAQ wa. "

msgid "wikibody2"
msgstr "Bẹ WIKI wò nípa títẹ̀ lórí wúnrẹ̀n àtòjọ-ẹ̀yàn WIKI. "

msgid "communitybody1"
msgstr "Ìṣàfikún ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀ la máa ń lò fún Ilú OLPC tí a lè wòye nípa títẹ̀ lórí wúnrẹ̀n àtòjọ-ẹ̀yàn ÌRÒYÌN ÌLÚ. "

msgid "faqbody1"
msgstr "Kí ni Kọ̀ǹpútà Alágbèéká $100 náà wà fún gan? Ẹ̀rọ $100 tí à ń gbèrò náà dá lé Linux pẹ̀lú ìṣàfihàn móòdù oníméjì—àwọn méjèèjì ló ní àwọ̀ kíkún, móòdù Ẹ̀rọ $100 tí à ń gbèrò náà dá lé Linux pẹ̀lú ìṣàfihàn móòdù oníméjì—àwọn méjèèjì ló ní àwọ̀ kíkún, móòdù transmissive DVD àti ẹ̀yàn ìṣàfihàn kejì tó lè tan òjìji dúdú àti funfun, tó si jẹ́ ìtànná oòrùn tó ṣeékà ní ìwọ̀n ìmúsí àwòrán 3×. Kọ̀ǹpútà alágbèéká náà máa ní elétò kọ̀ǹpútà 500MHz àti 128MB DRAM pẹ̀lú ọpọlọ Fíláàṣì 500MB, kò ní sí àwo dísíìkì ṣùgbọ́n ó máa ní àwọn ààlà-ìfibọ̀ USB mẹ́rin. Àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká náà máa ní bọ́dúbaǹdì aláìlókùn, èyí á gbà wọ́n láyè láti lè ṣiṣẹ́ papọ ní alátagbà agbègbè. Kọ̀ǹpútà alágbèéká kọ̀ọ̀kan á lè bá àwọn aládùúgbò tó súnmọ jù sọ̀rọ̀, ìṣẹ̀dá alátagbà agbègbè pàjáwìrì wáyé nì yẹn. Àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká náà máa lo agbá́ra àtinùdá (tó lè ká pọ̀)́ yóò sì lè ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun, kò kàn ní lè fi oye àkójọpọ̀-ẹ̀rí ńlá pamọ́ ni àti ẹ̀yàn ìṣàfihàn kejì tó jẹ́ òjìji dúdú àti funfun, tó si jẹ́ ìtànná oòrùn aṣeékà ní ìwọ̀n ìmúsí àwòrán 3×. Kọ̀ǹpútà alágbèéká náà máa ní elétò kọ̀ǹpútà 500MHz àti 128MB DRAM pẹ̀lú ọpọlọ Fíláàṣì 500MB, kò ní sí àwo dísíìkì ṣùgbọ́n ó máa ní àwọn ààlà-ìfibọ̀ USB mẹ́rin. Àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká náà máa ní bọ́dúbaǹdì aláìlókùn, èyí á gbà wọ́n láyè láti lè ṣiṣẹ́ papọ ní alátagbà agbègbè. Kọ̀ǹpútà alágbèéká kọ̀ọ̀kan á lè bá àwọn aládùúgbò tó súnmọ jù sọ̀rọ̀, ìṣẹ̀dá alátagbà agbègbè pàjáwìrì wáyé nì yẹn. Àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká náà máa lo agbá́ra àtinùdá (tó lè kápọ̀) yóò sì lè ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun, kò kàn ní lè fi oye àkójọpọ̀-ẹ̀rí ńlá pamọ́ ni. "

msgid "faqbody2"
msgstr "Wo àwọn ìbéèrè wa tí wọ́n sábà máa ń bèrè nípa títẹ̀ lórí wúnrẹ̀n àtòjọ-ẹ̀yàn FAQ. "

msgid "pressbody1"
msgstr "Wo àtòjọ àwọn ìjáde ìròyìn nípa títẹ̀ lórí wúnrẹ̀n àtòjọ-ẹ̀yàn ÌGBÉRÒYÌNJÁDE. "

msgid "downloadbody1"
msgstr "Ṣàgbéwọlé àwọn àwòrán (ó sì lè jẹ́ ẹ̀yà-ara kọ̀ǹpútà àìfojúrí àti àwọn nǹkan mìíràn) wà nílẹ̀, nípa títẹ̀ lórí wúnrẹ̀n àtòjọ-ẹ̀yàn ÀGBÉWỌLÉ. "

msgid "mapbody1"
msgstr "A fi àwọ̀ kóòdù máàpù àgbáyé tiwa ṣe ìtọ́kasí: (àwọ̀ ewé) àwọn orílẹ̀-èdè tí a fẹ́ páílọ̀tì; (red) those countries we plan to include in the post-launch phase; (àwọ̀ ọsàn) àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ti fi ìfẹ́ hàn si ní ìpele Ẹ̀ka-Ẹ̀kọ́ tàbí tó ga ju bẹ́ẹ̀ lọ; àti (yẹ́lò) àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ń wá àtìlẹ́yìn ìjọba. "

#: faq.html
msgid "heading1"
msgstr "ÀWỌN ÌBÉÈRÈ TÍ A SÁBÀ MÁA Ń BÈRÈ "

msgid "heading2"
msgstr "Ìdáhùn àwọn ìbéèrè Nicholas Negroponte, tó jẹ́ alága fún Kọ̀ǹpútà Alágbèéká fún Ọmọ Kọ̀ọ̀kan lórí ète náà. "

msgid "question1"
msgstr "́Kí ni Kọ̀ǹpútà alágbèéká $100 náà gan? "

msgid "answer1"
msgstr "Ẹ̀rọ $100 tí à ń gbèrò náà dá lé Linux pẹ̀lú ìṣàfihàn móòdù oníméjì—àwọn méjèèjì ló ní àwọ̀ kíkún, móòdù transmissive DVD àti ẹ̀yàn ìṣàfihàn kejì tó lè tan òjìji dúdú àti funfun, tó si jẹ́ ìtànná oòrùn tó ṣeékà ní ìwọ̀n ìmúsí àwòrán 3×. Kọ̀ǹpútà alágbèéká náà máa ní elétò kọ̀ǹpútà 500MHz àti 128MB DRAM pẹ̀lú ọpọlọ Fíláàṣì 500MB, kò ní sí àwo dísíìkì ṣùgbọ́n ó máa ní àwọn ààlà-ìfibọ̀ USB mẹ́rin. Àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká náà máa ní bọ́dúbaǹdì aláìlókùn, èyí á gbà wọ́n láyè láti lè ṣiṣẹ́ papọ ní alátagbà agbègbè. Kọ̀ǹpútà alágbèéká kọ̀ọ̀kan á lè bá àwọn aládùúgbò tó súnmọ jù sọ̀rọ̀, ìṣẹ̀dá alátagbà agbègbè pàjáwìrì wáyé nì yẹn. Àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká náà máa lo agbá́ra àtinùdá (tó lè ká pọ̀)́ yóò sì lè ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun, kò kàn ní lè fi oye àkójọpọ̀-ẹ̀rí ńlá pamọ́ ni. "

msgid "question2"
msgstr "kí ló dé tí àwọn ọmọdé tó wá ní àwọn orílẹ̀-èdè tó ń dàgbà sókè nílò àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká? "

msgid "answer2"
msgstr "́Àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká jẹ́ fèrèsé àti irinṣẹ́: Ó jẹ́ férèsé sínú ayé àti irinṣẹ́ láti fi ronú. Wọ́n jẹ́ ọ̀nà àrà fún gbogbo àwọn ọmọdé láti kọ́ ẹ̀kọ́ nípasẹ̀ àjọṣepọ̀ àti àbẹ̀wò òmìnira. "

msgid "question3"
msgstr "́́Kí ló dé tí kò fi jẹ́ kọ̀ǹpútà ojú-iṣẹ́, tàbí—èyí tó tún dára jù ú—ẹ̀rọ ojú-iṣẹ́ alátùndáá? "

msgid "answer3"
msgstr "Àwọn kọ̀ǹpútà ojú-iṣẹ́ kò wọ́n to, ṣùgbọ́n gbígbé kiri ṣe pàtàkì pàápàá jùlọ gbígbé kọ̀ǹpútà náà lọ sílé ní àṣálẹ́. Àwọn ọ̀mọdé ní àwọn orílẹ̀-èdè tó ń dàgbà sókè nílò ìmọ̀-ẹ̀rọ ìwòyí, pàápàá jùlọ ẹ̀yà-ara kọ̀ǹpútà afojúrí tó rọ́kú àti ẹ̀yà-ara kọ̀ǹpútà alárà tuntun. Iṣẹ́ tí a ṣe láì pẹ́ ní Maine fi iyì ńlá tó wà nínú lílo kọ̀ǹpútà alágbèéká nínú gbogbo iṣẹ́ ìwé àti fún eré síṣe hàn. Gbígbé kọ̀ǹpútà alágbèéká náà wálé máa fún gbogbo ẹbí níṣẹ́ ṣe. Ní abúlé kan ní Cambodia níbi tí a ti ń ṣiṣẹ́, kò sí iná mọ̀nàmọ́ná níbẹ̀, kọ̀ǹpútà alágbèéká náà ló jẹ́ orísun ìmọ́lẹ̀ tó mọ́lẹ̀ jù nínú ilé náà.
Ní àkótán, nípa àwọn ẹ̀rọ alátùndáá: Tí a bá fojú inú wo àwọn kọ̀ǹpútà ojú-iṣẹ́ bí mílíọ̀nù ọgọ́rùn ún tí a ti lò. Ẹyọ kọ̀ọ̀kan wọn ló máa nílò àkíyèsí ènìyàn wákàtí kọ̀ọ̀kan láti tun ṣe, tun kì, kí wọ́n sì bójúto. Iṣẹ́ ẹgbẹ̀rún márùndínláàdọ́ta ọdún nìyẹn. Báyìí, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé à ń gba ni níyànjú láti ṣe àtúndá àwọn kọ̀ǹpútà tí a ti lò, síbẹ̀ èyí kì í se ọ̀nà àbáyọ fún Kọ̀ǹpútà Alágbèéká fún Ọmọ Kọ̀ọ̀kan."

msgid "question4"
msgstr "Báwo ló ṣe lè ṣeé ṣe tí ìná rẹ̀ kò fi ní hán? "

msgid "answer4"
msgstr "* Ní àkọ́kọ́, kí á mú kí ìná ìṣàfihàn náà wálẹ̀. Ìran ẹ̀rọ-àkọ́kọ́ náà yóò ní ìṣàfihàn móòdù oníméjì aláràtuntun, tó dúró fún àwọn ìlọsíwájú sí àwọn ìṣàfihàn LCD tí a sábà máa ń rí nínú àwọn ẹ̀rọ-ìṣeré DVD. A lè lo àwọn ìṣàfihàn yìí nínú ìmúsí àwòrán dúdú àti funfun tó ga nínú ìtànná oòrùn tó mọ́lẹ̀—gbogbo ìná rẹ̀ kú sí $35.
* Èkejì, a máa yọ ọ̀ra yẹn kúrò nínú àwọn ètò kọ̀ǹpútà náà. Àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká òde-òní ti ń sanra jù. Ìdá-méjì nínú ìdá-mẹ́ta ẹ̀yà-ara kọ̀ǹpútà àìfojúrí là ń lo láti bójútó ìdá kan tókù. Ó sí máa ń ṣe àwọn ojuṣe kan náà ní oríṣi ọ̀nà mẹ́sàn án ọ̀tọ̀tọ̀.
* Ẹ̀kẹta, a máa ta àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká náà ní ọ̀pọ̀ (ní mílíọ́ọ̀nù) tààrà sí àwọn ẹ̀ka ẹ̀kọ́, tí wọ́n lè pín wọn gẹ́gẹ́ bí i àwọn ìwé-àkànlò. "

msgid "question5"
msgstr "́Kí ló ṣe kókó níbẹ̀ tí ọmọ kọ̀ọkan ṣe máa ní kọ̀ǹpútà? Kí ni kò tọ̀nà pẹ̀lú àwọn gbọ̀ngán ìráyè ìlú? "

msgid "answer5"
msgstr "Kò sẹ́ ni tó ronú nípa àwọn pẹ́ńsù ìlú—àwọn ọmọdé ní ti wọn. Wọ́n jẹ́ àwọn irinṣẹ́ tí a lè ronú pẹ̀lú, kò hán fún ohun tí a kò lè lò láti siṣẹ́ àti eré, ìyàwòrán, kíkọ-ìwé àti ìṣirò. Kọ̀ǹpútà lè jẹ́ ọ̀kan náà ṣùgbọ́n kí wọ́n lágbára ju ra wọn lọ. Ní àfikún, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìdí ló tún ṣe kókó fún ọmọ láti ninǹkan—bọ́ọ̀lù, ọmọ lángidi, tàbí ìwé—tí a ó sì ṣe ìtọjú àwọn nǹkan yìí dáadáa pẹ̀lú ìfẹ́ àti ìtọ́jú tó péye."

msgid "question6"
msgstr "Ìdarapọ̀ ńkọ́? Ṣé iṣẹ́ tẹ́líkọmunikéṣàn kò hán jù ní àwọn ìlú tó ṣẹ̀ ń dàgbà sókè? "

msgid "answer6"
msgstr "Nígbà tí àwọn ẹ̀rọ yìí bá ta láti inú àpótí náà síta, wọn yóò ṣe alátagbà awọnú-ara tí ara wọn, ọ̀gbà-sọ́gbà. MIT àti Media Lab lati kọ́kọ́ ṣe é. A tún ń ṣàbẹ̀wò àwọn ọ̀nà tí a lè gbà darapọ̀ sí eegun-ẹ̀yìn Ítánẹ́ẹ̀tì ní owó pọ́ọ́kú. "

msgid "question7"
msgstr "Kí ni ohun tí kọ̀ǹpútà alágbèéká $1000 lè ṣe tí ẹ̀yà $100 kò lè ṣe? "

msgid "answer7"
msgstr "Ète náà kò pọ̀. A kàn fẹ́ kó jẹ́ pé Kọ̀ǹpútà alágbèéká $100 náà á fẹ́rẹ̀ lè ṣe ohun gbogbo. Ohun tí kò kàn ni ṣe ni pé, kò ní lè fi àkójọpọ̀-ẹ̀rí ńlá pamọ́. "

msgid "question8"
msgstr "Báwo la ṣe máa tà wọ́n? "

msgid "answer8"
msgstr "Àwọn ìjọba la máa ta àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká náà fún, ká lè pin fún àwọn ọmọdé nípasẹ̀ àwọn ilé-iwé. Èyí dá lé ètò kọ̀ǹpútà alágbèéká fún ọmọ kọ̀ọ̀kan. A ti kọ́kọ́ jíròrò pẹ̀lú China, India, Brazil, Argentina, Egypt, Nigeria, àti Thailand. Ní àfikún si, àwọn ẹ̀rọ díẹ̀ kan tí a fún wa la máa lò láti yan àwọn ìlú tó ti gòkè àgbà ní àwon orílẹ̀-èdè mìíràn. A ó sì máa ṣe ẹ̀yà tí a máa fi ṣòwò ní apá kan. "

msgid "question9"
msgstr "Ìgbà wo ló ń retí pé àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká yìí máa dé ọjà? Kí lo rí gẹ́gẹ́ bí i àwọn ìdíwọ́ tí wọ́n ga jù? "

msgid "answer9"
msgstr "Ìṣètò alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ wa ni láti ní àwọn tí yóò ṣetán láti lè gbé wọ́n lọ ní òpin ọdún 2006 tàbí ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 2007. Ìṣelọ́pọ̀ máa bẹ̀rẹ̀ lẹ́yìn tí a bá ti bèrè fún bí àwọn ẹ̀rọ mílíọ́ọ̀nù márùn ún sí mẹ́wàá, tí a dẹ̀ tí sanwó wọn sílẹ̀.
Ohun tí yóò jẹ́ ìdíwọ́ ńlá ni láti ṣe iṣẹ́ lọ́pọ̀ mílíọ́ọ̀nù ọgọ́rùn ún ohunkóhun. Èyí kì í ṣe ti ìpèsè nìkan-ìṣòro ọwọ́dọ́wọ́, ṣùgbọ́n ìṣòro iṣẹ́-ọnà. Ìwọ̀n náà ń ṣe ségesège ṣùgbọ́n ohun tí àwọn ilé-iṣẹ́ kan ń dá lábàá fún wa yà mí lẹ́nu. Ó sì jọ wí pé bí i ààbọ̀ àwọn ìṣòro náà ti ṣẹ́ nípa ìlérí tí wọ́n ṣe. "

msgid "question10"
msgstr "́Ta ló ṣe iṣẹ́-ọnà ògidì (ODM) kọ̀ǹpútà alágbèéká $100 gan? "

msgid "answer10"
msgstr "Quanta Computer Inc. ti ìlú Taiwan la yàn gẹ́gẹ́ bí oníṣẹ́ ọnà ògidì (ODM) fún ìdáwọ́lé kọ̀ǹpútà $100 náà. A ṣe ìpinnu náà lẹ́yìn tí bọ́ọ̀dù ṣe àyẹ̀wò àwọn ìfowólé láti ọ̀dọ̀ àwọn ilé-iṣẹ́ tó lè máa ṣe nǹkan lọ́pọ̀.
A dá Quanta Computer Inc sílẹ̀ ní ọdún 1988 ní ìlú Taiwan. Wọ́n ti ta ọjà tó lé ní bílíọ́ọ̀nù mẹ́wàá dọ́la ti Amẹ́ríkà US $10 billion, Quanta ní olùṣe lọ́pọ̀ kọ̀ǹpútà alágbèéká PC tó pọ̀jù lágbàáyé. Ilé-iṣẹ́ náà tún ń ṣe àwọn fóònù alágbèéká, àwọn LCD TV àti àwọn sáfà àti àwọn iṣẹ́ ìpamọ́. Ní àfikún Quanta tún ṣi gbọ̀ngán R&D, Quanta R&D Complex (QRDC) ní Taiwan tí iye rẹ̀ jẹ́ igba mílíọ́ọ̀nù dọ́là ti Amẹ́ríkà, US $200 million. Ohun-èlò tí a ṣí ní Q3 ti ọdún 2005 ní ààyè ilẹ̀ ìgbọ̀nwọ́n ẹsẹ̀ mílíọ́ọ̀nù méjì lé ìdá méjì, 2.2 million àti ipá láti gba àwọn oníṣẹ́-ẹ̀rọ ẹgbẹ̀rún méje, 7,000. "

msgid "question11"
msgstr "Báwo ní a ṣe máa ṣètò ète yìí? "

msgid "answer11"
msgstr "Kọ̀ǹpútà Alágbèéká fún Ọmọ Kọ̀ọ̀kan (OLPC) tó wà ní Delaware ló ṣe kọ̀ǹpútà alágbèéká $100. Ó jẹ́ àjọ aṣẹ̀dá láńfààní, tí a ṣẹ̀dá láti ọwọ́ àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ẹ̀ka MIT Media Lab láti ṣe ọnà rẹ, láti ṣe é lọ́pọ̀ kí wọ́n sì pín àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká tí kò hán tí kò hán náà láti pèsè fún gbogbo ọmọdé lágbàáyé láti láyè sí ìmọ̀ àti àwọn ọ̀nà ẹ̀kọ́ ìgbàlódé. OLPC dá lé àwọn tíọ́rì ẹ̀kọ́ constructionist tí Seymour Papert, ní èyí tí Alan Kay náà darapọ̀ mọ́ àti àwọn ìlànà tí a ṣọ yéké nínú ìwé Nicholas Negroponte tó ń jẹ́ Being Digital,. Àwọn Tó jẹ́ ògbóǹtaàgì alájọṣe olùdásílẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ ní Advanced Micro Devices (AMD), Brightstar, Google, News Corporation, Nortel, àti Red Hat.
Nicholas Negroponte ló jẹ́ alága fún Kọ̀ǹpútà Alágbèéká fún Ọmọ Kọ̀ọ̀kan, Lou Jepsen sì ń ṣiṣẹ́ bí i òṣìṣẹ́ àgbà ìmọ̀-ẹ̀rọ. Àwọn Ọ̀gá àgbà mìíràn tó kópa nínú ṣíṣe Kọ̀ǹpútà Alágbèéká $100 ni: Walter Bender, Michail Bletsas, V. Michael Bove, Jr., David Cavallo, Benjamin Mako Hill, Joseph Jacobson, Alan Kay, Tod Machover, Seymour Papert, Mitchel Resnick, àti Ted Selker.
Design Continuum ń gbèrò iṣẹ́-ọnà lórí kọ̀ǹpútà alágbèéká. "

msgid "date"
msgstr "February 2006"#: people.html

#: press.html

msgid "milestones"
msgstr "MILESTONES"

#: download.html

msgid "license"
msgstr "These works are licensed under a"

msgid "deed"
msgstr ""

msgid "dccredit"
msgstr "Image and illustration credit:"

msgid "imagelabel1"
msgstr "CONCEPT IMAGES"

msgid "clicklarger"
msgstr "Click for larger versions."

msgid "po"
msgstr "Download the project PO file here."

#: map.html

msgid "mapkey1"
msgstr "(green) those countries we plan to pilot"

msgid "mapkey2"
msgstr "(orange) those countries who have expressed interest at the Ministry-of-Education level or higher"

msgid "mapkey3"
msgstr "(yellow) those countries who are currently seeking government support"

msgid "mapkey4"
msgstr "(red) those countries we plan to include in the post-launch phase"

#: members.html

msgid "membersbody1"
msgstr "One Laptop per Child is a non-profit association to promote the worldwide improvement of education through the design, manufacturing, distribution and deeper understanding of affordable computing and telecommunications for learning by children, particularly in developing countries.

Our members are:"